ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 20:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Tí o bá lọ bá àwọn ọ̀tá rẹ jagun, tí o sì rí àwọn ẹṣin, àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun wọn tí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ jù ọ́ lọ, má bẹ̀rù wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì wà pẹ̀lú rẹ.+

  • Sáàmù 46:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Ọlọ́run ni ibi ààbò wa àti okun wa,+

      Ìrànlọ́wọ́ tó wà lárọ̀ọ́wọ́tó ní àkókò wàhálà.+

  • Róòmù 8:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́