Àìsáyà 10:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ẹ̀yin èèyàn mi tó ń gbé ní Síónì, ẹ má bẹ̀rù nítorí ará Ásíríà tó ti máa ń fi ọ̀pá lù yín,+ tó sì máa ń gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè sí yín bíi ti Íjíbítì.+
24 Torí náà, ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ẹ̀yin èèyàn mi tó ń gbé ní Síónì, ẹ má bẹ̀rù nítorí ará Ásíríà tó ti máa ń fi ọ̀pá lù yín,+ tó sì máa ń gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè sí yín bíi ti Íjíbítì.+