2 Kíróníkà 32:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Hẹsikáyà ló dí orísun omi+ Gíhónì+ tó wà lápá òkè pa, ó sì darí rẹ̀ tààràtà lọ sí ìwọ̀ oòrùn Ìlú Dáfídì.+ Hẹsikáyà ṣàṣeyọrí nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.
30 Hẹsikáyà ló dí orísun omi+ Gíhónì+ tó wà lápá òkè pa, ó sì darí rẹ̀ tààràtà lọ sí ìwọ̀ oòrùn Ìlú Dáfídì.+ Hẹsikáyà ṣàṣeyọrí nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.