Mátíù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jòhánù wọ aṣọ tí wọ́n fi irun ràkúnmí ṣe, ó sì de àmùrè tí wọ́n fi awọ ṣe mọ́ ìbàdí rẹ̀.+ Eéṣú àti oyin ìgàn ni oúnjẹ rẹ̀.+
4 Jòhánù wọ aṣọ tí wọ́n fi irun ràkúnmí ṣe, ó sì de àmùrè tí wọ́n fi awọ ṣe mọ́ ìbàdí rẹ̀.+ Eéṣú àti oyin ìgàn ni oúnjẹ rẹ̀.+