2 Àwọn Ọba 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, wọ́n sọ fún un pé: “Ọkùnrin náà wọ aṣọ onírun,+ ó sì de àmùrè awọ mọ́ ìbàdí rẹ̀.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sọ pé: “Èlíjà ará Tíṣíbè ni.”
8 Torí náà, wọ́n sọ fún un pé: “Ọkùnrin náà wọ aṣọ onírun,+ ó sì de àmùrè awọ mọ́ ìbàdí rẹ̀.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sọ pé: “Èlíjà ará Tíṣíbè ni.”