1 Àwọn Ọba 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Sólómọ́nì yíjú sí Áṣítórétì,+ abo ọlọ́run àwọn ọmọ Sídónì àti Mílíkómù,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì. 1 Àwọn Ọba 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+
5 Sólómọ́nì yíjú sí Áṣítórétì,+ abo ọlọ́run àwọn ọmọ Sídónì àti Mílíkómù,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.
7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+