1 Àwọn Ọba 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èèyàn Ọlọ́run+ kan wá láti Júdà sí Bẹ́tẹ́lì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ fún un, nígbà tí Jèróbóámù dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ+ láti mú ẹbọ rú èéfín.
13 Èèyàn Ọlọ́run+ kan wá láti Júdà sí Bẹ́tẹ́lì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ fún un, nígbà tí Jèróbóámù dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ+ láti mú ẹbọ rú èéfín.