Jeremáyà 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Èyí ni ohun tí Jèhófà sọ nípa Ṣálúmù*+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà tó ń jọba nípò Jòsáyà bàbá rẹ̀,+ ẹni tó jáde kúrò ní ibí yìí: ‘Kò ní pa dà mọ́.
11 “Èyí ni ohun tí Jèhófà sọ nípa Ṣálúmù*+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà tó ń jọba nípò Jòsáyà bàbá rẹ̀,+ ẹni tó jáde kúrò ní ibí yìí: ‘Kò ní pa dà mọ́.