Jeremáyà 26:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ran Jeremáyà lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa fi í lé àwọn èèyàn náà lọ́wọ́ láti pa á.+
24 Àmọ́ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ran Jeremáyà lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa fi í lé àwọn èèyàn náà lọ́wọ́ láti pa á.+