1 Kíróníkà 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà tí Ásúbà kú, Kélẹ́bù fẹ́ Éfúrátì,+ ó sì bí Húrì+ fún un.