ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 15:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àwọn ìlú tó wà ní ìkángun ẹ̀yà Júdà lápá ibi tí ààlà Édómù+ wà ní gúúsù nìyí: Kábúséélì, Édérì, Jágúrì,

  • Jóṣúà 15:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Hasari-ṣúálì, Bíá-ṣébà,+ Bisiotáyà,

  • Jóṣúà 19:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+

  • Jóṣúà 19:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Hasari-ṣúálì,+ Bálà, Ésémù,+

  • Nehemáyà 11:25-27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ní ti àwọn ibi tí wọ́n tẹ̀ dó sí pẹ̀lú àwọn pápá wọn, àwọn kan lára àwọn èèyàn Júdà ń gbé ní Kiriati-ábà+ àti àwọn àrọko rẹ̀,* ní Díbónì àti àwọn àrọko rẹ̀, ní Jekabúsélì+ àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, 26 ní Jéṣúà, ní Móládà,+ ní Bẹti-pélétì,+ 27 ní Hasari-ṣúálì,+ ní Bíá-ṣébà àti àwọn àrọko rẹ̀,*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́