2 Kíróníkà 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí wọ́n ń kó owó táwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà jáde,+ àlùfáà Hilikáyà rí ìwé Òfin+ tí Jèhófà fún wọn nípasẹ̀* Mósè.+
14 Nígbà tí wọ́n ń kó owó táwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà jáde,+ àlùfáà Hilikáyà rí ìwé Òfin+ tí Jèhófà fún wọn nípasẹ̀* Mósè.+