2 Àwọn Ọba 25:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+