1 Sámúẹ́lì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Láàárín ọdún kan,* Hánà lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ+ rẹ̀ ní Sámúẹ́lì,* torí ó sọ pé, “ọwọ́ Jèhófà ni mo ti béèrè rẹ̀.”
20 Láàárín ọdún kan,* Hánà lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ+ rẹ̀ ní Sámúẹ́lì,* torí ó sọ pé, “ọwọ́ Jèhófà ni mo ti béèrè rẹ̀.”