-
Nehemáyà 11:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn aṣọ́bodè ni Ákúbù, Tálímónì+ àti àwọn arákùnrin wọn tó ń ṣọ́ àwọn ẹnubodè, wọ́n jẹ́ méjìléláàádọ́sàn-án (172).