1 Sámúẹ́lì 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ,*+ ìwọ̀n irin tí wọ́n fi ṣe aṣóró ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ṣékélì;* ẹni tó ń bá a gbé apata sì ń lọ níwájú rẹ̀.
7 Igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ,*+ ìwọ̀n irin tí wọ́n fi ṣe aṣóró ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ṣékélì;* ẹni tó ń bá a gbé apata sì ń lọ níwájú rẹ̀.