ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 24:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kí Jèhófà ṣe ìdájọ́ láàárín èmi àti ìwọ,+ kí Jèhófà sì bá mi gbẹ̀san lára rẹ,+ àmọ́ mi ò ní jẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ọ.+

  • 1 Sámúẹ́lì 24:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Kí Jèhófà jẹ́ onídàájọ́, kí ó sì dájọ́ láàárín èmi àti ìwọ. Yóò rí i, yóò gba ẹjọ́ mi rò,+ yóò dá ẹjọ́ mi, yóò sì gbà mí lọ́wọ́ rẹ.”

  • 1 Sámúẹ́lì 26:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jèhófà ló máa san òdodo àti ìṣòtítọ́ kálukú+ pa dà fún un, torí pé Jèhófà fi ọ́ lé mi lọ́wọ́ lónìí, àmọ́ mi ò fẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ẹni àmì òróró Jèhófà.+

  • Sáàmù 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;

      Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+

      Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́