Ìṣe 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ó tún fún Ábúráhámù ní májẹ̀mú ìdádọ̀dọ́,*+ ó sì bí Ísákì,+ ó dádọ̀dọ́ rẹ̀* ní ọjọ́ kẹjọ,+ Ísákì sì bí* Jékọ́bù, Jékọ́bù sì bí àwọn olórí ìdílé* méjìlá (12).
8 “Ó tún fún Ábúráhámù ní májẹ̀mú ìdádọ̀dọ́,*+ ó sì bí Ísákì,+ ó dádọ̀dọ́ rẹ̀* ní ọjọ́ kẹjọ,+ Ísákì sì bí* Jékọ́bù, Jékọ́bù sì bí àwọn olórí ìdílé* méjìlá (12).