2 Sámúẹ́lì 6:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Dáfídì ń fi gbogbo ara jó yí ká níwájú Jèhófà; ní gbogbo àkókò náà, Dáfídì wọ* éfódì+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe. 15 Dáfídì àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì ń gbé Àpótí+ Jèhófà bọ̀ pẹ̀lú igbe ayọ̀+ àti ìró ìwo.+
14 Dáfídì ń fi gbogbo ara jó yí ká níwájú Jèhófà; ní gbogbo àkókò náà, Dáfídì wọ* éfódì+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe. 15 Dáfídì àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì ń gbé Àpótí+ Jèhófà bọ̀ pẹ̀lú igbe ayọ̀+ àti ìró ìwo.+