2 Sámúẹ́lì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi.+ Tí ó bá ṣe àìtọ́, màá fi ọ̀pá àti ẹgba àwọn ọmọ aráyé*+ bá a wí. Lúùkù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ohùn kan+ wá dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, ẹni tí mo ti yàn.+ Ẹ fetí sí i.”+ Hébérù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bí àpẹẹrẹ, èwo nínú àwọn áńgẹ́lì ni Ọlọ́run sọ fún rí pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”?+ Tó sì tún sọ fún pé: “Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi”?+
14 Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi.+ Tí ó bá ṣe àìtọ́, màá fi ọ̀pá àti ẹgba àwọn ọmọ aráyé*+ bá a wí.
5 Bí àpẹẹrẹ, èwo nínú àwọn áńgẹ́lì ni Ọlọ́run sọ fún rí pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”?+ Tó sì tún sọ fún pé: “Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi”?+