-
1 Kíróníkà 27:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Dáfídì kò ka àwọn tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sísàlẹ̀, nítorí pé Jèhófà ti ṣèlérí láti sọ Ísírẹ́lì di púpọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+ 24 Jóábù ọmọ Seruáyà bẹ̀rẹ̀ sí í ka àwọn èèyàn, àmọ́ kò kà wọ́n parí; Ọlọ́run bínú sí Ísírẹ́lì* nítorí nǹkan yìí,+ a kò sì kọ iye náà sínú àkọsílẹ̀ ìtàn ìgbà Ọba Dáfídì.
-