Léfítíkù 26:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+
25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+