Diutarónómì 28:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà máa mú kí àrùn ṣe ọ́ títí ó fi máa pa ọ́ run ní ilẹ̀ tí o fẹ́ lọ gbà.+ Jeremáyà 24:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá rán idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn* sí wọn,+ títí wọ́n á fi ṣègbé kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn àti àwọn baba ńlá wọn.”’” Émọ́sì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ‘Mo rán àjàkálẹ̀ àrùn sáàárín yín bíi ti Íjíbítì.+ Mo fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín,+ mo sì gba àwọn ẹṣin yín.+ Mo mú kí òórùn àwọn tó kú ní ibùdó yín gba afẹ́fẹ́ kan;+Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’ ni Jèhófà wí.
10 Màá rán idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn* sí wọn,+ títí wọ́n á fi ṣègbé kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn àti àwọn baba ńlá wọn.”’”
10 ‘Mo rán àjàkálẹ̀ àrùn sáàárín yín bíi ti Íjíbítì.+ Mo fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín,+ mo sì gba àwọn ẹṣin yín.+ Mo mú kí òórùn àwọn tó kú ní ibùdó yín gba afẹ́fẹ́ kan;+Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’ ni Jèhófà wí.