ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:59
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Jèhófà máa mú kí àwọn àrùn tó le gan-an ṣe ìwọ àti ọmọ rẹ, àwọn ìyọnu+ tó lágbára gan-an tí kò sì ní lọ bọ̀rọ̀, pẹ̀lú àwọn àìsàn tó le gan-an tí kò sì ní lọ bọ̀rọ̀.

  • Jeremáyà 15:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín!

      Idà máa pa àwọn kan lára yín!+

      Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín!

      Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+

  • Ìsíkíẹ́lì 7:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Idà wà níta,+ àjàkálẹ̀ àrùn àti ìyàn sì wà nínú. Idà ni yóò pa ẹnikẹ́ni tó bá wà ní pápá, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn sì máa run àwọn tó bá wà nínú ìlú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́