Jeremáyà 14:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bí mo bá jáde lọ sínú pápá, tí mo sì wò,Àwọn tí idà pa ni mò ń rí!+ Bí mo bá sì wá sínú ìlú,Àwọn àrùn tí ìyàn fà ni mò ń rí!+ Nítorí wòlíì àti àlùfáà ti lọ káàkiri ní ilẹ̀ tí wọn ò mọ̀.’”+ Ìsíkíẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+
18 Bí mo bá jáde lọ sínú pápá, tí mo sì wò,Àwọn tí idà pa ni mò ń rí!+ Bí mo bá sì wá sínú ìlú,Àwọn àrùn tí ìyàn fà ni mò ń rí!+ Nítorí wòlíì àti àlùfáà ti lọ káàkiri ní ilẹ̀ tí wọn ò mọ̀.’”+
12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+