Léfítíkù 26:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+ Jeremáyà 24:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá rán idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn* sí wọn,+ títí wọ́n á fi ṣègbé kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn àti àwọn baba ńlá wọn.”’”
25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+
10 Màá rán idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn* sí wọn,+ títí wọ́n á fi ṣègbé kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn àti àwọn baba ńlá wọn.”’”