1 Àwọn Ọba 8:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní àkókò yẹn, Sólómọ́nì sọ̀rọ̀, ó ní: “Jèhófà sọ pé inú ìṣúdùdù tó kàmàmà+ ni òun á máa gbé. 13 Mo ti kọ́ ilé ológo kan parí fún ọ, ibi tó fìdí múlẹ̀ tí wàá máa gbé títí láé.”+ Sáàmù 135:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ìyìn ni fún Jèhófà láti Síónì,+Ẹni tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù.+ Ẹ yin Jáà!+
12 Ní àkókò yẹn, Sólómọ́nì sọ̀rọ̀, ó ní: “Jèhófà sọ pé inú ìṣúdùdù tó kàmàmà+ ni òun á máa gbé. 13 Mo ti kọ́ ilé ológo kan parí fún ọ, ibi tó fìdí múlẹ̀ tí wàá máa gbé títí láé.”+