Éfésù 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ máa fi àwọn sáàmù àti ìyìn sí Ọlọ́run àti àwọn orin ẹ̀mí bá ara yín sọ̀rọ̀, kí ẹ máa kọrin+ sí Jèhófà,*+ kí ẹ sì máa fi ohùn orin+ gbè é nínú ọkàn yín,
19 Ẹ máa fi àwọn sáàmù àti ìyìn sí Ọlọ́run àti àwọn orin ẹ̀mí bá ara yín sọ̀rọ̀, kí ẹ máa kọrin+ sí Jèhófà,*+ kí ẹ sì máa fi ohùn orin+ gbè é nínú ọkàn yín,