2 Kíróníkà 11:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Rèhóbóámù ń gbé Jerúsálẹ́mù, ó sì kọ́ àwọn ìlú olódi sí Júdà. 6 Ó tipa bẹ́ẹ̀ kọ́* Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ Étámì, Tékóà,+ Émọ́sì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ Émọ́sì,* ọ̀kan lára àwọn tó ń sin àgùntàn láti Tékóà,+ èyí tó gbọ́ nínú ìran nípa Ísírẹ́lì nígbà ayé Ùsáyà+ ọba Júdà àti nígbà ayé Jèróbóámù+ ọmọ Jóáṣì,+ ọba Ísírẹ́lì, ní ọdún méjì ṣáájú ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé.+
5 Rèhóbóámù ń gbé Jerúsálẹ́mù, ó sì kọ́ àwọn ìlú olódi sí Júdà. 6 Ó tipa bẹ́ẹ̀ kọ́* Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ Étámì, Tékóà,+
1 Ọ̀rọ̀ Émọ́sì,* ọ̀kan lára àwọn tó ń sin àgùntàn láti Tékóà,+ èyí tó gbọ́ nínú ìran nípa Ísírẹ́lì nígbà ayé Ùsáyà+ ọba Júdà àti nígbà ayé Jèróbóámù+ ọmọ Jóáṣì,+ ọba Ísírẹ́lì, ní ọdún méjì ṣáájú ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé.+