Mátíù 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Ẹ máa béèrè, a sì máa fún yín;+ ẹ máa wá kiri, ẹ sì máa rí; ẹ máa kan ilẹ̀kùn, a sì máa ṣí i fún yín;+ Hébérù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bákan náà, láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa, torí ẹnikẹ́ni tó bá ń tọ Ọlọ́run wá gbọ́dọ̀ gbà gbọ́ pé ó wà àti pé òun ló ń san èrè fún àwọn tó ń wá a tọkàntọkàn.+ Jémíìsì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run, á sì sún mọ́ yín.+ Ẹ wẹ ọwọ́ yín mọ́, ẹ̀yin ẹlẹ́ṣẹ̀,+ kí ẹ sì wẹ ọkàn yín mọ́,+ ẹ̀yin aláìnípinnu.
7 “Ẹ máa béèrè, a sì máa fún yín;+ ẹ máa wá kiri, ẹ sì máa rí; ẹ máa kan ilẹ̀kùn, a sì máa ṣí i fún yín;+
6 Bákan náà, láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa, torí ẹnikẹ́ni tó bá ń tọ Ọlọ́run wá gbọ́dọ̀ gbà gbọ́ pé ó wà àti pé òun ló ń san èrè fún àwọn tó ń wá a tọkàntọkàn.+
8 Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run, á sì sún mọ́ yín.+ Ẹ wẹ ọwọ́ yín mọ́, ẹ̀yin ẹlẹ́ṣẹ̀,+ kí ẹ sì wẹ ọkàn yín mọ́,+ ẹ̀yin aláìnípinnu.