Sáàmù 58:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+ Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+ Mátíù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ máa yọ̀, kí inú yín sì dùn gidigidi,+ torí èrè yín+ pọ̀ ní ọ̀run, torí bí wọ́n ṣe ṣe inúnibíni sí àwọn wòlíì tó wà ṣáájú yín nìyẹn.+ Mátíù 6:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+
11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+
3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+
12 Ẹ máa yọ̀, kí inú yín sì dùn gidigidi,+ torí èrè yín+ pọ̀ ní ọ̀run, torí bí wọ́n ṣe ṣe inúnibíni sí àwọn wòlíì tó wà ṣáájú yín nìyẹn.+
33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+