1 Sámúẹ́lì 17:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn mẹ́ta tó dàgbà jù lára àwọn ọmọkùnrin Jésè ti tẹ̀ lé Sọ́ọ̀lù lọ sí ogun.+ Orúkọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó lọ sójú ogun ni Élíábù+ àkọ́bí, Ábínádábù+ ìkejì àti Ṣámà ìkẹta.+
13 Àwọn mẹ́ta tó dàgbà jù lára àwọn ọmọkùnrin Jésè ti tẹ̀ lé Sọ́ọ̀lù lọ sí ogun.+ Orúkọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó lọ sójú ogun ni Élíábù+ àkọ́bí, Ábínádábù+ ìkejì àti Ṣámà ìkẹta.+