2 Àwọn Ọba 25:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+ Jeremáyà 40:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n sọ fún un pé: “Ṣé o kò mọ̀ pé Báálísì, ọba àwọn ọmọ Ámónì,+ ti rán Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà láti wá pa ọ́?”*+ Ṣùgbọ́n Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù kò gbà wọ́n gbọ́.
22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+
14 Wọ́n sọ fún un pé: “Ṣé o kò mọ̀ pé Báálísì, ọba àwọn ọmọ Ámónì,+ ti rán Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà láti wá pa ọ́?”*+ Ṣùgbọ́n Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù kò gbà wọ́n gbọ́.