-
2 Àwọn Ọba 23:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọba wá pàṣẹ fún Hilikáyà+ àlùfáà àgbà àti àwọn àlùfáà yòókù àti àwọn aṣọ́nà pé kí wọ́n kó gbogbo nǹkan èlò tí àwọn èèyàn ṣe fún Báálì àti fún òpó òrìṣà*+ àti fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run jáde nínú tẹ́ńpìlì Jèhófà. Lẹ́yìn náà, ó dáná sun wọ́n ní ìta Jerúsálẹ́mù lórí ilẹ̀ onípele tó wà ní Kídírónì, ó sì kó eérú wọn lọ sí Bẹ́tẹ́lì.+
-