1 Àwọn Ọba 6:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 ní ọdún kọkànlá, oṣù Búlì* (ìyẹn, oṣù kẹjọ), wọ́n parí gbogbo iṣẹ́ ilé náà bó ṣe wà nínú àwòrán ilé kíkọ́ rẹ̀.+ Torí náà, ọdún méje ni ó fi kọ́ ọ.
38 ní ọdún kọkànlá, oṣù Búlì* (ìyẹn, oṣù kẹjọ), wọ́n parí gbogbo iṣẹ́ ilé náà bó ṣe wà nínú àwòrán ilé kíkọ́ rẹ̀.+ Torí náà, ọdún méje ni ó fi kọ́ ọ.