-
2 Àwọn Ọba 23:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Nítorí náà, àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ fi kẹ̀kẹ́ ẹṣin gbé òkú rẹ̀ láti Mẹ́gídò wá sí Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì sin ín sí sàréè rẹ̀. Lẹ́yìn náà, àwọn èèyàn ilẹ̀ náà mú Jèhóáhásì ọmọ Jòsáyà, wọ́n fòróró yàn án, wọ́n sì fi í jọba ní ipò bàbá rẹ̀.+
31 Ẹni ọdún mẹ́tàlélógún (23) ni Jèhóáhásì+ nígbà tó jọba, oṣù mẹ́ta ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútálì+ ọmọ Jeremáyà láti Líbínà.
-