Oníwàásù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo ṣe àwọn iṣẹ́ ńlá.+ Mo kọ́ àwọn ilé fún ara mi;+ mo gbin àwọn ọgbà àjàrà fún ara mi.+