1 Àwọn Ọba 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọdún mẹ́tàlá (13) ló gba Sólómọ́nì láti kọ́ ilé* rẹ̀,+ títí ó fi parí ilé náà látòkèdélẹ̀.+ 1 Àwọn Ọba 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó kọ́ ilé* tí á máa gbé ní àgbàlá kejì+ sẹ́yìn Gbọ̀ngàn* náà, iṣẹ́ ọnà wọn sì jọra. Ó tún kọ́ ilé kan tí ó dà bíi Gbọ̀ngàn yìí fún ọmọbìnrin Fáráò, ẹni tí Sólómọ́nì fi ṣe aya.+
8 Ó kọ́ ilé* tí á máa gbé ní àgbàlá kejì+ sẹ́yìn Gbọ̀ngàn* náà, iṣẹ́ ọnà wọn sì jọra. Ó tún kọ́ ilé kan tí ó dà bíi Gbọ̀ngàn yìí fún ọmọbìnrin Fáráò, ẹni tí Sólómọ́nì fi ṣe aya.+