1 Àwọn Ọba 22:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Jèhóṣáfátì tún ṣe àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì* láti máa fi kó wúrà+ wá láti Ófírì, ṣùgbọ́n wọn ò lè lọ torí pé àwọn ọkọ̀ òkun náà fọ́ ní Esioni-gébérì.+ Sáàmù 45:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba wà lára àwọn obìnrin ọlọ́lá rẹ. Ayaba* dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, a fi wúrà Ófírì+ ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́.
48 Jèhóṣáfátì tún ṣe àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì* láti máa fi kó wúrà+ wá láti Ófírì, ṣùgbọ́n wọn ò lè lọ torí pé àwọn ọkọ̀ òkun náà fọ́ ní Esioni-gébérì.+
9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba wà lára àwọn obìnrin ọlọ́lá rẹ. Ayaba* dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, a fi wúrà Ófírì+ ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́.