Oníwàásù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo kó fàdákà àti wúrà jọ fún ara mi,+ ìṣúra* àwọn ọba àti ti àwọn ìpínlẹ̀.+ Mo kó àwọn akọrin lọ́kùnrin àti lóbìnrin jọ fún ara mi, títí kan ohun tó ń múnú ọmọ aráyé dùn gidigidi, ìyẹn obìnrin, àní ọ̀pọ̀ obìnrin.*
8 Mo kó fàdákà àti wúrà jọ fún ara mi,+ ìṣúra* àwọn ọba àti ti àwọn ìpínlẹ̀.+ Mo kó àwọn akọrin lọ́kùnrin àti lóbìnrin jọ fún ara mi, títí kan ohun tó ń múnú ọmọ aráyé dùn gidigidi, ìyẹn obìnrin, àní ọ̀pọ̀ obìnrin.*