1 Sámúẹ́lì 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bí wọ́n ṣe wọlé, tí ó sì rí Élíábù,+ ó sọ pé: “Ó dájú pé ẹni àmì òróró Jèhófà ló dúró yìí.” 1 Sámúẹ́lì 17:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn mẹ́ta tó dàgbà jù lára àwọn ọmọkùnrin Jésè ti tẹ̀ lé Sọ́ọ̀lù lọ sí ogun.+ Orúkọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó lọ sójú ogun ni Élíábù+ àkọ́bí, Ábínádábù+ ìkejì àti Ṣámà ìkẹta.+
13 Àwọn mẹ́ta tó dàgbà jù lára àwọn ọmọkùnrin Jésè ti tẹ̀ lé Sọ́ọ̀lù lọ sí ogun.+ Orúkọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó lọ sójú ogun ni Élíábù+ àkọ́bí, Ábínádábù+ ìkejì àti Ṣámà ìkẹta.+