-
2 Kíróníkà 11:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn tó wá láti gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì tí wọ́n ti pinnu láti máa wá Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì tẹ̀ lé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì wá sí Jerúsálẹ́mù láti rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn.+
-