1 Àwọn Ọba 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgọ́rin (480) ọdún lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ní ọdún kẹrin lẹ́yìn tí Sólómọ́nì di ọba lórí Ísírẹ́lì, ní oṣù Sífì*+ (ìyẹn, oṣù kejì), ó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé Jèhófà.*+ 1 Àwọn Ọba 6:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ní ọdún kẹrin, oṣù Sífì,* wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀;+
6 Ní ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgọ́rin (480) ọdún lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ní ọdún kẹrin lẹ́yìn tí Sólómọ́nì di ọba lórí Ísírẹ́lì, ní oṣù Sífì*+ (ìyẹn, oṣù kejì), ó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé Jèhófà.*+