-
1 Àwọn Ọba 14:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Lọ sọ fún Jèróbóámù pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Mo gbé ọ dìde láti àárín àwọn èèyàn rẹ, kí n lè sọ ọ́ di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+
-