Diutarónómì 27:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gbẹ́ ère+ tàbí tó ṣe ère onírin,*+ tó jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣẹ́ ọnà,* tó sì gbé e pa mọ́.’ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’*) 2 Kíróníkà 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèróbóámù wá yan àwọn àlùfáà tirẹ̀ fún àwọn ibi gíga+ àti fún àwọn ẹ̀mí èṣù+ tó rí bí ewúrẹ́* àti fún àwọn ère ọmọ màlúù tí ó ṣe.+
15 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gbẹ́ ère+ tàbí tó ṣe ère onírin,*+ tó jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣẹ́ ọnà,* tó sì gbé e pa mọ́.’ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’*)
15 Jèróbóámù wá yan àwọn àlùfáà tirẹ̀ fún àwọn ibi gíga+ àti fún àwọn ẹ̀mí èṣù+ tó rí bí ewúrẹ́* àti fún àwọn ère ọmọ màlúù tí ó ṣe.+