2 Kíróníkà 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run fa ìṣubú Ahasáyà bó ṣe wá sọ́dọ̀ Jèhórámù; nígbà tó dé, ó tẹ̀ lé Jèhórámù lọ sọ́dọ̀ Jéhù+ ọmọ ọmọ* Nímúṣì, ẹni tí Jèhófà ti fòróró yàn láti pa ilé Áhábù run.*+
7 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run fa ìṣubú Ahasáyà bó ṣe wá sọ́dọ̀ Jèhórámù; nígbà tó dé, ó tẹ̀ lé Jèhórámù lọ sọ́dọ̀ Jéhù+ ọmọ ọmọ* Nímúṣì, ẹni tí Jèhófà ti fòróró yàn láti pa ilé Áhábù run.*+