Jeremáyà 26:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí àwọn ìjòyè Júdà gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, wọ́n wá láti ilé* ọba sí ilé Jèhófà, wọ́n sì jókòó sí ibi àtiwọ ẹnubodè tuntun ti Jèhófà.+
10 Nígbà tí àwọn ìjòyè Júdà gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, wọ́n wá láti ilé* ọba sí ilé Jèhófà, wọ́n sì jókòó sí ibi àtiwọ ẹnubodè tuntun ti Jèhófà.+