Jeremáyà 36:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bárúkù bá ka ọ̀rọ̀ Jeremáyà sókè látinú àkájọ ìwé* náà ní ilé Jèhófà sí etí gbogbo àwọn èèyàn náà, ní yàrá* Gemaráyà+ ọmọ Ṣáfánì+ adàwékọ,* ní àgbàlá òkè tó wà ní àtiwọ ẹnubodè tuntun ilé Jèhófà.+
10 Bárúkù bá ka ọ̀rọ̀ Jeremáyà sókè látinú àkájọ ìwé* náà ní ilé Jèhófà sí etí gbogbo àwọn èèyàn náà, ní yàrá* Gemaráyà+ ọmọ Ṣáfánì+ adàwékọ,* ní àgbàlá òkè tó wà ní àtiwọ ẹnubodè tuntun ilé Jèhófà.+