2 Kíróníkà 29:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin ọmọ Léfì. Ní báyìí, ẹ ya ara yín sí mímọ́,+ kí ẹ ya ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín sí mímọ́, kí ẹ sì mú ohun àìmọ́ kúrò nínú ibi mímọ́.+
5 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin ọmọ Léfì. Ní báyìí, ẹ ya ara yín sí mímọ́,+ kí ẹ ya ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín sí mímọ́, kí ẹ sì mú ohun àìmọ́ kúrò nínú ibi mímọ́.+