2 Sámúẹ́lì 24:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí Dáfídì dìde ní àárọ̀, Jèhófà bá wòlíì Gádì+ tó jẹ́ aríran Dáfídì sọ̀rọ̀, ó ní: 12 “Lọ sọ fún Dáfídì pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ohun mẹ́ta ni màá fi síwájú rẹ. Mú ọ̀kan tí o fẹ́ kí n ṣe sí ọ.”’”+ 1 Kíróníkà 29:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran
11 Nígbà tí Dáfídì dìde ní àárọ̀, Jèhófà bá wòlíì Gádì+ tó jẹ́ aríran Dáfídì sọ̀rọ̀, ó ní: 12 “Lọ sọ fún Dáfídì pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ohun mẹ́ta ni màá fi síwájú rẹ. Mú ọ̀kan tí o fẹ́ kí n ṣe sí ọ.”’”+
29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran